The Bible / Bíbélì - The Gospel According to Saint Matthew / Ìhìnrere Gẹ́gẹ́ Bí Ìwé Mímọ́ Mátíù: Tranzlaty English Yorùbá
Paperback Published on: 14/01/2026; Language: Yoruba
Price: £11.99
wordery
wordery
Synopsis
5:2 And he opened his mouth, and taught them, saying,
5:2 O si yà ẹnu rẹ`, o si kọ´ wọn, wipe:
5:3 Blessed are the poor in spirit: for theirs is the kingdom of heaven.
5:3 Alabukún-fun li awọn talaka ni ẹmi: nitori tiwọn ni ijọba ọrun.
5:4 Blessed are they that mourn: for they shall be comforted.
5:4 Alabukún-fun li awọn ti nsọ`fọ nitori nwọn o ni itunu.
5:5 Blessed are the meek: for they shall inherit the earth.
5:5 Alabukún-fun li awọn ọlọkàn-tutu: nitori nwọn o jogún aiye.
5:6 Blessed are they which do hunger and thirst after righteousness: for they shall be filled.
5:6 Alabukún-fun li awọn ti ebi npa ati ti ongbẹ ngbẹ si ododo: nitori nwọn o yo.
Publisher information
- Publisher: Tranzlaty
- ISBN: 9783692296722
- Number of pages: 148
- Dimensions: 203 x 127 x 9 mm
- Languages: Yoruba
